IBADAN OMO AJEGBIN JEKARAUN, AFI KARAUN FO’ORI MU.


image

Ohun tio fa ti gbolohun yi se
jeyo ninu oriki ile ibadan, pelu ohun ti yoruba ma n pe
ni OORI.

Nigba nhun ni, ogun ko Ibadan akoko latari aso egun
to si larin’ja eyi ti se ewo, to si mu ki alaafin pe
Ibadan ni ija, Lagelu ati awon ebi re to kore ogun, a
ma fi ikarahun igbin fo oori (eko) mu ninu igbo ti won fi
ara pamo si leyin igba ti won ba je igbin inu ikarahun
yi, fun idi eyi won a mo pe Omo ibadan ni, omo aje
gbin je ikarahun tabi omo afi ikarahun fo ori mu.