Ìṣe tí kò kúrò nínú Àṣà Yorùbá


Ìṣe tí kò kúrò nínú Àṣà Yorùbá

Ní ọjọ́ etí ti o kọja, sá dédé ni àgó mi dùn, ìyá mi ni òun pé. Ǹjẹ́ òun bọ̀ sì ilé lónìí? Tí ó bá jẹ bẹẹ má jẹ kóju agogo marun lọ ooo.

Ní ìgbà ìkásìn, bí ohun burúkú bá mi ṣẹlẹ̀ ni inú ọjà ní ilẹ Yorùbá, àwọn ará ọjà yio se wa idi, wá má d’ ifá pẹ̀lú. Ní ìgbà miran wọn yóò kan pá ọjà ni (ẹnikẹ́ni kò ní sí ìsọ̀) ̀ ni ìgbà miran wọn yóò gbé ẹbọ.

Kò fi bẹ jẹ ìyàlẹ́nu pé pẹlu awọn ẹṣin miran ti ọtí di ona ami gba pe Elédùa bí (Ìgbàgbọ́ àti imole) àwọn ará ọjà sì tún mi ṣe ìpèsè bí àmì pá ọjà, gbígbé ẹbọ àti orò sì jẹ àwọn Ìṣe tí kò tí wó sìn nínú Àṣà ìpẹ̀tù sì nkan ni ilẹ̀ Yorùbá.

Ó ṣẹlẹ̀ pé ikú ọ̀wọwọ̀ tí fẹ́ di manli nínú ọjà tí ó wà ní ọ̀nà àdúgbò wá, èyí lò sì fà tí wọn fi pá ọjà, tí wọn sì tún gbé ẹbọ. Abalọ̀ ababọ̀ rẹ ni pé àwọn ará àgbègbè yí payá kí má lu orò èyí tí ó fà tí ìyà mi fi pè mí láti súré kọjá ní bí ọjà na kí ó tó di àkókò tí wọn yóò gbé orò àti ẹbọ

“Esu is Not Satan” | Interview with Orisa Priestess Ifawemimo Omitonade | by Kola Tubosun | Brittle Paper


Ifá and Òrìṣà worship are the original spiritual practices in Africa especially in Yorùbáland. In Yorùbáland where the religion comes from, the worship, rituals and traditions were mainly family-based. The practice of Ifá/Orìsà is a spiritual path to transformation, a transformation from the inside out, that begins with you as an individual and ends with you as an individual. Ifá worship is different from Òrìṣà worship.

http://brittlepaper.com/2016/04/kola-ifa-interview/


@iyabadan on Twitter